Released on March 28, 2026

Thumbnail

[Pre-Chorus]

Ninu march past yi ‘ma March fast

Tori dandan ni ka bori last last

Mi o calm down, mi o lie down

Ti m’ba rehin Ese, mi i ni stand down

Ninu march past yi ‘ma March fast

Tori dandan ni ka bori last last

Mi o calm down, mi o lie down

Ti m’ba rehin Ese, mi i ni stand down

[Intro]

Ache ache ti

Che Che ti

Okay oun sise

Yeah

[Chorus]

K’eku Ile k’ogbo, ko pe t’oko parowa fun o!

Koko laa ro’fa aditi, k’esu ye ma to ‘mo’lorun wo

Iwaju iwaju, lopa ebiti n re si o. Omo ogun la je, Iwaju l’ase n mu wa re

K’eku Ile k’ogbo, ko pe t’oko parowa fun o!

Koko laa ro’fa aditi, k’esu ye ma to ‘mo’lorun wo

Iwaju iwaju, lopa ebiti n re si o. Omo ogun la je, Iwaju l’ase n mu wa re

[Rap Verse]

Yeah

Ati kekere ma ni Jesu Kristi ti pattern mi

Ti ma sere ninu varana Pelu pata mi

Gun gI grova f’igi se moto pelu catas mi

Ta matun sha gbin, omo memories yi n scatter mi

Moonlight tales nigbayen dabi siesta

Storyline n sere bi water, omo na fiesta

Round table Pele sister mi, a ma gbo fabuu. Chest am

A tun gbo story eni to f’igbe to Le crest her

Irinajo omo adamu, BÄBA Loye se

Repete logun aye mi to ti dabi ko Le se

Mo ti ketan faya ri ma gbese bi pe mo fe she

Akalolo ti o Le da pe Mummy, tun Di rapper se

Irinajo mi dabI parade, pe mo n se march past

Igba mi attention, slow March abi ki n March fast

Life a tun ju mi niju kiju, ma tun catch fast

Ekun ti mo ti sun gbeyin bayi laa je last batch

Esu yi mi mo yepe, mo dide Gbongan piri

Ko mo pe ikuu Jesu ma mu igbala wa, it’s a pirry

Bi iji ja, ka mi lorule, ma tun ko at the count of three

Ki’le oba Jo, ewa laa bu si. o sure fun mi ni lyrics

Irin ajo mi negba, ko se so l’ede geesi

Lati ijebu, mo di Ajala, mi o ribi yeesi

Jesu p’ona mi mo titi mo FI wa n’ife nsiyin

O la mi loju, to mi, otun ko mi ni many lessons

Mo ti gba apa lorishi ti ko Le jo oju ara mo

No retreat, no surrender ni mo se para mo

Eni ti oro mi o ye ni ki n ma kanra mo

Esu te, o foju mi whi ina, mo ti gara tan

Mo ti de bayi, happy soul, mi o fo fun depression

Mo te pa mo se Oluwa lai create impression

Mi o ni pe ju Lori igbonse, ki ma lo ko infection

Journey ti ma cover jin, o wise ki n lo discretion