Released on March 28, 2026

Thumbnail

[Chorus]

Baba wa, Baba wa tin be l’orun…

Baba wa, Baba wa tin be l’orun…

Baba wa, Baba wa tin be l’orun…

Baba wa, Baba wa tin be l’orun…


[Verse 1]

Yeah,BÄBA mi Oke, BÄBA mi ti n be l’orun

Ko s’abuja lorun ope, afi ki n be Olorun

Mi o pe mi o ye, mii sele fonu

BÄBA gbe mi ga, e de Le FI mi korun

Inside life, Olorun orun mo Kere gan

Mo Le ma ka botoboto, but mo’n sere gan

Meta kobo igberaga, mi o ni shile gan

E ni ba ma da also f’ole, BÄBA a paa Laro tan

Agbatan laa gbole, BÄBA shaanu mi

Ma je ki iji to n ja Ile mi yii shi panu mi

Ma je ki ota yo mi, ki oso ma je fan mi

Ki n Le pada renu dupe baba p’eti shanu mi


[Chorus]

Baba wa, Baba wa tin be l’orun…

Baba wa, Baba wa tin be l’orun… (Ka bowo fun oruko re oo)

Baba wa, Baba wa tin be l’orun… (Ka bowo fun oruko re oo)

Baba wa, Baba wa tin bе l’orun…


[Verse 2]

Ko si ipa kan, to kere ju ti mo Le sa

Irinkе rindo, ko sere ti mo Le sa

Ko so olori oko bambam ti mo Le ba

Ko s’Ifa Abi awo, ti mo Le ba

Olorun orun mi nikan ni mo gbojule

Baba, Omo, Emi mimo, meta lokan kogun de

Gbogbo emi aimo to ba ri won a pojude

Tori ina T’Olorun gbe Kari ju ti Lalude

Baba segun Funmi. Ba mi p’ota lenumo

Ki won ma ni bawo ni mo se se, ki n ma menumo

Mu mi debi giga, ki n Le goke Erinmo

Ki n Le ti oke to ga ju ti ma je mimo mimo


[Chorus]

Baba wa, Baba wa tin be l’orun…

Baba wa, Baba wa tin be l’orun…

Baba wa, Baba wa tin be l’orun…

Baba wa, Baba wa tin be l’orun…

Baba wa, Baba wa tin be l’orun…

Baba wa, Baba wa tin be l’orun… (Ka bowo fun oruko re oo)

Baba wa, Baba wa tin be l’orun… (Ka bowo fun oruko re oo)

Baba wa, Baba wa tin be l’orun…

(Speaking in Tongues)

Commando