Released on February 6, 2026

5K Views

Thumbnail

[Intro: Shoday]

Oh, baba yẹ, dáhùn s'ọ̀rọ̀ mi

Oh, my maye, ma ma k'ohùn mi

One big transaction, tó ma change story mi

Malaika tó n gbé're, jọ wá gbé'rẹ s'odo mi

Oh, babá ye, dáhùn s'ọ̀rọ̀ mi (Ob—, Obah)

Oh my maye, ma ma k'ohùn mi (Wah dem a say?)

One big transaction, to ma change story mi

Malaika tó n pín'rẹ́, jọ̀wọ́ pín'rẹ d'odọ̀ mi


[Verse 1: Shoday]

Wọn ni Naija ṣi ma dùn, but you dey America

E go better la ti n gbó la t'aye Abacha

Owo t'ọmọde bá kọ́ rí, á fi jẹ akara

If I see first money, mo ma sá lọ Canada


[Chorus: Shoday]

Oh, baba ye, dáhùn s'ọ̀rọ̀ mi (Shoday, kí lo dé?)

Oh, my maye, ma ma k'ohùn mi (Hmm)

One big transaction, to ma change story mi

Malaika tó n pín'rẹ́, jọ̀wọ́ pin're d'odo mi (Oh, babá yè)

Oh, babá ye, dáhùn s'ọ̀rọ̀ mi (Dáhùn sọ̀rọ̀ mi)

Oh, my maye, ma ma k'ohùn mi (Ma ma k'ohùn mi)

One big transaction, tó ma change story mi (Ehn)

Malaika tó n pínrẹ́, jọ̀wọ́ pin're d'odo mi (Oh, babá yè)


[Verse 2: Bhadboi OML]

Ibí e ní gbégbé kò ma gbé, ibè ló ma gbé (Ibè ló má gbé)

Ọjà to ni gbégbé kò ma gbé, gbogbo ẹ ló ma gbé (Gbogbo ẹ ló ma gbé)

Purple Haze ninu brown rizzler, high me my canister

Oh my maye ye-ye, wa gbé mi trabaye, ye-ye-ye

Ayy, it's going, it's going, olomi kò ní s'oṣi, kò ní s'ofo

They're trolling their father, I’m stoning pẹ̀lú kpoli, pẹ̀lú coco

Kò sí problem, kò sí yawa, kò sí story, kò sí glory, ọmọ ologo

Ah, dorime fún ọmọ ọpẹ́ (Dorime fún ọmọ ọpẹ́)

Ọmọ oro mi wá pẹ (Ọmọ oro mi wá pẹ)

[Chorus: Shoday, Choir]

Oh, baba ye

Oh, baba ye, dáhùn s'ọ̀rọ̀ mi (Dáhùn s'ọ̀rọ̀ mi)

Oh, my maye, ma ma k'ohùn mi (Ma ma k'ohùn mi)

One big transaction, tó ma change story mi (Ehn)

Malaika tó n pín're, jọ̀wọ́ pín're d'odo mi

Oh, baba ye

Oh, baba ye, dáhùn s'ọ̀rọ̀ mi (Dáhùn, dáhùn, dáhùn; dáhùn sọ̀rọ̀ mi)

Oh, my maye, ma ma k'ohùn mi (Ma ma k'ohùn mi)

One big transaction, to ma change story mi (Ehn)

Malaika tó n gbé'rẹ, jọ wá gbé'rẹ d'odo mi