Sha Guide

By Portable

Thumbnail

[Intro]

Tuti on the beat

‎Omolalomi again they call me portable baby (Popo when)

‎[Chorus]

‎Ija wa ija osi (Sha guide)

‎Da ti e mo (Sha guide)

‎Eyan wa eyan osi (Sha guide)

‎E get why (Sha guide)

‎Sabo plus oluwore (Sha guide)

‎Wa ṣe Ike si Inu idi (Sha guide)

‎Wa fenu gba pata ni idi (Sha guide)

‎Elo lo wa la account e? (Sha guide)

‎Ha, ogun laye (Sha guide)

‎Lomu Abu Abel se ogun ayeta (Sha guide)

‎If you price you go pay (Sha guide)

‎Olowo lo n pe la alaye (Sha guide)

‎[Verse 1]

‎Ọmọ dudu omo pupa

‎Gbogbo won ni mo ti pa

‎Elo ni price e?

‎Mo maa fi universe gba pata idi e

‎Mo maa fún e ni lion

‎To gbe money gun dani (Sha guide)

‎Mufasa mufasa (Sha guide)

‎Lion ekun mefa (Sha guide)

‎Ta lo fa e la so ya

‎Sunmo eni ti iwo ba ja

‎Ogbeni gbe ori sa nibiti tan ti yin sakabula

‎[Chorus]

‎Ija wa ija osi (Sha guide)

‎Da ti e mo (Sha guide)

‎Eyan wa eyan osi (Sha guide)

‎E get why (Sha guide)

‎Sabo plus oluwore (Sha guide)

‎Wa se Ike si Inu idi (Sha guide)

‎Wa fenu gba pata ni idi (Sha guide)

‎Elo lo wa la account e? (Sha guide)

‎Ha, ogun laye (Sha guide)

‎Lomu Abu Abel se ogun ayeta (Sha guide)

‎If you price you go pay (Sha guide)

‎Olowo lo n pe la alaye (Sha guide)

‎[Verse 2]

‎Ọmọ ki lo fi se ibadi? Oya ligali

‎Se Saudi lo ti se badi?

‎Nobody is calling me

‎Oya Ligali ligali mo tun ti de

‎Ohun to ba wu won ni kan so

‎Ligali ligali awa tun ti de

‎T'owo ba de gongon aso

‎Money gun mefa fun eyan kan

‎Baby lion meta fun enikan

‎E fun l'orun pa

‎Eyi l'òrùka

‎[Chorus]

‎Ija wa ija osi (Sha guide)

‎Da ti e mo (Sha guide)

‎Eyan wa eyan osi (Sha guide)

‎E get why (Sha guide)

‎Sabo plus oluwore (Sha guide)

‎Wa se Ike si inu idi (Sha guide)

‎Wa fenu gba pata ni idi (Sha guide)

‎Elo lo wa la account e? (Sha guide)

‎Ha, ogun laye (Sha guide)

‎Lomu Abu Abel se ogun ayeta (Sha guide)

‎If you price you go pay (Sha guide)

‎Olowo lo n pe ni alaye (Sha guide)


[Outro]

Tuti on the mix