[Verse 1]
Igba o lọ bi orere
Bo ba kọrò oṣi maa dun ah
Eni to ni sùúrù ki ṣ'ẹ̀yán kekere
Bo ba kan'lẹ, oṣi maa g'ọ̀kẹ, ah
[Pre-Chorus]
Bòó ba ṣe oun tọ fe, wọn maa k'ẹyin si e
Eh-ah-eh
Bo ba ṣe ti ẹ o, o ma jẹ ire fun ẹ
Eh-ah-eh
[Chorus]
Ọlánrewájú ọmọ ọba
Eh ma sure d'àgbà o
Wọn ni ko ṣe were, rọra ṣe
Eh ma sure d'àgbà o
Olóòótọ́ ko ni ku si bi ọtẹ o
Ọlánrewájú ọmọ mi, eh ma sure d'àgbà o
[Verse 2]
Igba o lọ bi orere
B'ọmọdé oku o, oṣi ma d'àgbà o
Ṣọra fun'ja, ṣọ ra f'ẹgbẹ-kẹ-gbẹ
Oun ti o to o, oṣi ma pọ daanu
[Pre-Chorus]
Gbogbo eni abi lo ma ku
Eh-ah-eh
Iwa ta wu lo ma ku ah
Eh-ah-eh
[Chorus]
Ọlánrewájú ọmọ ọba, eh ma sure d'àgbà o
Wọn ni ko ṣe were, rọra ṣe
Eh ma sure da gba oo
Olóòótọ́ ko ni ku sibi ọtẹ o
Ọlanrewaju ọmọ mi, e ma sure da gba o
Olóòótọ́ ko ni ku s'ipo ika o
Olóòótọ́ ko ni ku s'ibi ote o
Ọlánrewájú ọmọ ọba, eh ma sure d'àgbà o
Ọlánrewájú ọmọ mi, eh ma sure d'àgbà o