Àkọ́kọ́

By Brymo

On Ésan

Released on September 9, 2021

Thumbnail

[Verse 1]

Èmi ní, èmi l'éni náà

Ọkùnrin mẹta at'abo, t'on f'orin ko

Èmi ni, èmi l'ọmọ náà

Ọkùnrin mẹrin at'abo, wọn t'ẹnu mó

Mo la'nu, mó s'ọ̀rọ̀

Mo y'aké, mó f'ọ̀rọ̀

Ọmọ ọlọfọrọ, mo j'àkàrà ọfọrọ

Ẹ̀mi ni ah, èmi ni oh

Èmi ma l'éni t'on sọ n'ìgboro

Èmi ni yaa, èmi ni yoo

Àwọn màmá gàn soro ni pópó


[Chorus]

Wọ́n l'èmi l'àkoko

Wọ́n l'èmi l'àkoko, oh

Wọ́n l'èmi l'àkoko, ooh

Wọ́n l'èmi l'àkoko, ooh


[Verse 2]

Èmi ni, ọkùnrin náà

T'áwọn majesi sọ pé o m'orin gàn

Èmi ni, èmi l'ọmọ na

Gbọgbọ ará àdúgbò lọn t'ẹnu mo

Èmi bàbá olówó, mo ṣ'òwò, mo jèrè

Ìwà at'ọpọlọ l'on lò, àwọn ọ̀tá ti ru pọ

Ẹ̀mi ni ah, èmi ni oh

Èmi ma l'éni t'on sọ n'ìgboro

Èmi ni yaa, èmi ni yoo

Àwọn ọmọge re'di ni pópó


[Chorus]

Wọ́n l'èmi l'àkoko (Ìwọ l'àkoko)

Wọ́n l'èmi l'àkoko, ooh (Ìwọ l'àkoko o)

Wọ́n l'èmi l'àkoko, ooh (Ìwọ l'àkoko)

Wọ́n l'èmi l'àkoko, ooh (Ìwọ l'àkoko o)

Wọ́n l'èmi l'àkoko (Ìwọ l'àkoko)

Wọ́n l'èmi l'àkoko, ooh (Ìwọ l'àkoko o)

Wọ́n l'èmi l'àkoko, ooh (Ìwọ l'àkoko)

Wọ́n l'èmi l'àkoko, ooh (Ìwọ l'àkoko o)