Balloranking - Weekend Lyrics

Verse 1

O n bẹ nibẹ

Olowo lawọn nigga mi kẹ

All the shawty want to naked

As we dey enjoy every weekend

O n bẹ nibẹ

Olowo lawọn nigga mi kẹ

All the shawty want to naked

As we dey enjoy every weekend

Rọra mi a ṣe garagara

Tori olowo lo n se falafolo

Gba mi lọwọ gbarada

Laye mi k'emi ma lọ jẹba yo

Bakki dey go lẹsọ lẹsọ

Everything dey go leto leto

Ibadi to pọn sẹyin sẹyin

Ohun lo n mu ara mi yagaga

Ọlọrun lo n sọyan sọyan

Shawty ṣe mi diẹdiẹ

Ibaka ẹ ko gbọn, ko gbọn

Ohun lo n mu ọlọdẹ sa fun aja

Yeh, o tilẹ pẹpẹ

Rọra ma mi ilẹkẹ

Lalẹ yii o ma bẹbẹ

Ogogoro ti balẹ pepẹ

Chorus

Oh mami dancia

Ibaka rẹ fakia

Mo dẹ le gbe iya yẹn ka ma lọ abẹtẹ ka lọ lafia

Oh mami dancia

Ibaka rẹ fakia

Ọmọ, mo dẹ le gbe iya yẹn ka ma lọ abẹtẹ ka lọ lafia

Verse 2

I got pounds in my pocket

Awọn ọmọ mi wọn fi mi ṣere

Jack Daniel in my Jacket

Anytime ti n ba fẹ tibi tibi

Ye, o peleke

Abi ṣe mo foju jọ geh geh?

To ba dori papa o ma ferege

Wa ferege, a ferege

+234 wọn tẹka lọ

Ọmọ ti o jo ko ma gbata lọ

VVIP lawọn eleyii ko ma lọ fun ẹ ni akamọ

+234 wọn tẹka lọ

Ọmọ ti o jo ko ma gbata lọ

VVIP lawọn eleyii ko ma lọ fun ẹ ni akamọ

Chorus

Oh mami dancia

Ibaka rẹ fakia

Mo dẹ le gbe iya yẹn ka ma lọ abẹtẹ ka lọ lafia

Oh mami dancia

Ibaka rẹ fakia

Ọmọ, mo dẹ le gbe iya yẹn ka ma lọ abẹtẹ ka lọ lafia

Outro

Oh mami dancia