Balloranking & BhadBoi OML - Pami Lyrics

Verse 1

Ẹlẹyinju ẹgẹ mi apọnbeporẹ

Ṣe you go follow me go my kaba to ba dalẹ?

The way you dey whine your body make me wan confess

The way you dey whine your body

Chorus

Ma pa mi fun mama mi

Lẹekankan rọra gbẹsẹ

Ma pa mi fun baba mi

Lalẹ yii a ma dẹṣẹ

Ọmọ ma pa mi fun mama mi

Lẹekankan rọra gbẹsẹ

Ma pa mi fun baba mi

Lalẹ yii a ma dẹṣẹ

Verse 2

How much she wanti mo pe Jago

She say give me 5k mo gba LAPO

Dem say e loud but Colorado

Demma say e loud but Colorado

How much she wanti mo pe Jago

She say give me 5k mo gba LAPO

Dem say e loud but Colorado

Demma say e loud but Colorado

Refrain

Ọmọ ma gbẹsẹ lẹkọọkan

Ọmọ maa jijo Ba Wasi

Ọrọbọkibọ, kibọ, kibọ

Ọrọbọkibọ, kibọ, kibọrọki

Ọmọ ma gbẹsẹ lẹkọọkan

Ọmọ maa jijo Ba Wasi

Ọrọbọkibọ, kibọ, kibọ

Ọrọbọkibọ, kibọ, kibọrọki

Verse 3

Ọgẹnẹdo

Oheama jo wọn n la bi parago

Where you wan go ṣе na Toronto?

As ọmọ ologo

Ṣe ka gbori wọ Monaco, mm?

Jaye lavida local

Ki lo fẹ sọ mi da baby

Ọmọ jẹ ka kolobi yon

Drive, makе I be your conductor

Chorus

Ma pa mi fun mama mi

Lẹkọọkan rọra gbẹsẹ

Ma pa mi fun baba mi

Lalẹ yii a ma dẹṣẹ

Ọmọ ma pa mi fun mama mi

Lẹkọọkan rọra gbẹsẹ

Ma pa mi fun baba mi

Lalẹ yii a ma dẹṣẹ

Verse 4

How much she wanti mo pe Jago

She say give me 5k mo gba LAPO

Dem say e loud but Colorado

Demma say e loud but Colorado

How much she wanti mo pe Jago

She say give me 5k mo gba LAPO

Dem say e loud but Colorado

Demma say e loud but Colorado

Outro

Ọmọ ma gbẹsẹ lẹkọọkan

Ọmọ maa jijo Ba Wasi

Ọrọbọkibọ, kibọ, kibọ

Ọrọbọkibọ, kibọ, kibọrọki

Ọmọ ma gbẹsẹ lẹkọọkan

Ọmọ maa jijo Ba Wasi

Ọrọbọkibọ, kibọ, kibọ

Ọrọbọkibọ, kibọ, kibọrọki