Gratitude

By Asake

On M$NEY

Released on May 1, 2026

74K Views

Thumbnail

[Verse]

I no fit lie you, wetin my eye don see, ó pọ̀ gan (Hm-hm)

So many good wey man don do, but na bad dem go talk (Hm-hm)

Even Jesus Christ, the Lord, dem nail am for cross (Hm-hm)

You no fit please everybody, ọmọ, o mọ p'ẹnu l'ẹbọ o


[Pre-Chorus]

(It's not personal, rárá o)

Personal, rárá o, rárá o

No give me yawa o (Yawa o), no give me yawa o, yawa o

Ọmọ arayé kala o, tí o bá wá sí owó, wọ́n máa japa o

Don't take it personal (Ahn), owọ́ epo lọn bá'ni lá


[Chorus]

(Hmm)

Mo ṣ'oríre méje-méje (Hmm)

Orí mi, kó ma kọ́ blessing (Hmm)

Credit alert (Hmm)

Gratitude ṣa ni (Hmm)

Mo ṣ'oríre méje-méje (Mọ ṣ'ori re)

Orí mi, kó má kọ́ blessing (Orí mi)

Credit alert (Hmm)

Gratitude (Ṣa ni)


[Pre-Chorus]

It's not personal, rárá o (Rárá o)

Personal, rárá o, rárá o

No give me yawa o (Yawa o)

No give me yawa o, yawa o

Ọmọ arayé kala o (Kala), tí o bá sí owó wọ́n má japa o

Don't take it personal, owọ́ epo l'ọ́n bá'ni lá


[Chorus]

(Hmm)

Mo ṣ'oríre méje-méje (Ṣ'orírẹ)

Orí mi, kó máa kó blessing (Orí mi)

Credit alert (Hmm)

Gratitude ṣa ni

Mo ṣ'oríre méje-méje (Mo ṣ'orirẹ)

Orí mi, kó má kó blessing (Orí mi)

Credit alert (Hmm)

Gratitude (Ṣa ni)