Ojo to ru si ewuro

Lo ro si ireke

Se bi saati rahmoni baba ba wa se

Asese o la bijun

A tun se ni ma le

Koriko terin ba te ko ma tun dide

Oke agba ni mo gun yi o x4

E ma jen jaabo

Oke agba ni mo gun yi o x3

E ma jen jaabo

Omo to ba sisi dede

O ye ko ni igbadun

Adun obe o nbe ninu shasun

This one na the part 1

You never see the part 2

We are relevant just like your tattoo

Won ni mo saare wa mo saare

Mo de tun gbe eni wa, mo gbe eni wa

Mo de pe shalewa, pe shalеwa

Ko de lo gbe o ti wa, lo gbo ti wa eh

Ojo to ru si еwuro

Lo ro si ireke

Se bi saati rahmoni baba n ba wa se

Asese o la bijun

A tun se ni ma le

Koriko terin ba te ko ma tun dide

Oke agba ni mo gun yi o x4

E ma jen jaabo

Oke agba ni mo gun yi o x3

E ma jen jaabo

Ise leye ile se ko to fin se ise kole

Ise looka baba se to fi pooporo sole

Ise nla ni mo se kin to pa owo mi wa le

Ma je aye ori mi, ma fin amebo mi sole

Won ni mo saare wa mo saare

Mo de tun gbe eni wa, mo gbe eni wa

Mo de pe shalewa, pe shalewa

Ko de lo gbe o ti wa, lo gbo ti wa eh

Ojo to ru si ewuro

Lo ro si ireke

Se bi saati rahmoni baba n ba wa se

Asese o la bi jun

A tun se ni ma le

Koriko to terin ba te ko ma tun dide

Oke agba ni mo gun yi o x4

E ma jen jaabo

Oke agba ni mo gun yi o x3

E ma jen jaabo

Oke oke oke

E ma jen jaabo

Beat, chris, Underscore